Mat 17:20-21

Mat 17:20-21 YBCV

Jesu si wi fun wọn pe, Nitori aigbagbọ́ nyin ni: lõtọ ni mo sá wi fun nyin, Bi ẹnyin ba ni igbagbọ́ bi wóro irúgbin mustardi, ẹnyin o wi fun òke yi pe, Ṣi nihin lọ si ọ̀hun, yio si ṣi; kò si si nkan ti ẹ ki yio le ṣe. Ṣugbọn irú eyi ki ijade lọ bikoṣe nipa adura ati àwẹ̀.

Àwọn fídíò fún Mat 17:20-21

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú Mat 17:20-21