IWE iran Jesu Kristi, ọmọ Dafidi ọmọ Abrahamu. Abrahamu bí Isaaki; Isaaki si bí Jakọbu; Jakọbu si bí Juda ati awọn arakunrin rẹ̀; Juda si bí Faresi ati Sara ti Tamari; Faresi si bí Esromu; Esromu si bí Aramu; Aramu si bí Aminadabu; Aminadabu si bí Naaṣoni; Naaṣoni si bí Salmoni; Salmoni si bí Boasi ti Rakabu; Boasi si bí Obedi ti Rutu; Obedi si bí Jesse; Jesse si bí Dafidi ọba. Dafidi ọba si bí Solomoni lati ọdọ ẹniti o ti nṣe aya Uria; Solomoni si bí Rehoboamu; Rehoboamu si bí Abia; Abia si bí Asa; Asa si bí Jehosafati; Jehosafati si bí Joramu; Joramu si bí Osia; Osia si bí Joatamu; Joatamu si bí Akasi; Akasi si bí Hesekiah; Hesekiah si bí Manasse; Manasse si bí Amoni; Amoni si bí Josiah; Josiah si bí Jekoniah ati awọn arakunrin rẹ̀, nigba ikolọ si Babiloni. Lẹhin ikolọ si Babiloni ni Jekoniah bí Sealtieli; Sealtieli si bí Serubabeli; Serubabeli si bí Abiudu; Abiudu si bí Eliakimu; Eliakimu si bí Asoru; Asoru si bí Sadoku; Sadoku si bí Akimu; Akimu si bí Eliudu; Eliudu si bí Eleasa; Eleasa si bí Matani; Matani si bí Jakọbu
Kà Mat 1
Feti si Mat 1
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Mat 1:1-15
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò