Luk 6:21

Luk 6:21 YBCV

Alabukun-fun li ẹnyin ti ebi npa nisisiyi: nitoriti ẹ ó yo. Alabukun-fun li ẹnyin ti nsọkun nisisiyi: nitoriti ẹnyin ó rẹrin.

Àwọn fídíò fún Luk 6:21