Luk 4:43

Luk 4:43 YBCV

Ṣugbọn o si wi fun wọn pe, Emi kò le ṣaima wasu ijọba Ọlọrun fun ilu miran pẹlu: nitorina li a sá ṣe rán mi.

Àwọn fídíò fún Luk 4:43