Luk 24:15-16

Luk 24:15-16 YBCV

O si ṣe, nigbati nwọn mba ara wọn sọ, ti nwọn si mba ara wọn jirorò, Jesu tikararẹ̀ sunmọ wọn, o si mba wọn rìn lọ. Ṣugbọn a rú wọn li oju ki nwọn ki o máṣe le mọ̀ ọ.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ