EMI ti bá oju mi da majẹmu, njẹ emi o ha ṣe tẹjumọ wundia? Nitoripe kini ipin Ọlọrun lati ọrun wá, tabi kini ogún Olodumare lati oke ọrun wá? Kò ṣepe awọn enia buburu ni iparun wà fun, ati ìṣẹniṣẹ fun awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ? On kò ha ri ipa-ọ̀na mi, on kò ha si ka gbogbo iṣiṣe mi?
Kà Job 31
Feti si Job 31
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Job 31:1-4
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò