Joh 4:21

Joh 4:21 YBCV

Jesu wi fun u pe, Gbà mi gbọ́, obinrin yi, wakati na mbọ̀, nigbati kì yio ṣe lori òke yi, tabi Jerusalemu, li ẹnyin o ma sìn Baba.

Àwọn fídíò fún Joh 4:21