Joh 12:42-43

Joh 12:42-43 YBCV

Sibẹ ọ̀pọ ninu awọn olori gbà a gbọ́ pẹlu; ṣugbọn nitori awọn Farisi nwọn kò jẹwọ rẹ̀, ki a má bà yọ wọn kuro ninu sinagogu: Nitori nwọn fẹ iyìn enia jù iyìn ti Ọlọrun lọ.

Àwọn fídíò fún Joh 12:42-43