Joh 11:5-6

Joh 11:5-6 YBCV

Jesu si fẹran Marta, ati arabinrin rẹ̀, ati Lasaru. Nitorina nigbati o ti gbọ́ pe, ara rẹ̀ kò da, o gbé ijọ meji si i nibikanna ti o gbé wà.

Àwọn fídíò fún Joh 11:5-6