Joh 10:3

Joh 10:3 YBCV

On ni oludèna ṣilẹkun fun; awọn agutan si gbọ ohùn rẹ̀: o si pè awọn agutan tirẹ̀ li orukọ, o si ṣe amọ̀na wọn jade.

Àwọn fídíò fún Joh 10:3