Joh 1:43-44

Joh 1:43-44 YBCV

Ni ọjọ keji Jesu nfẹ jade lọ si Galili, o si ri Filippi, o si wi fun u pe, Mã tọ̀ mi lẹhin. Ara Betsaida ni Filippi iṣe, ilu Anderu ati Peteru.

Àwọn Fídíò tó Jẹmọ́ ọ