Enoku si wà li ọgọta ọdún o lé marun, o si bí Metusela: Enoku si ba Ọlọrun rìn li ọ̃dunrun ọdún lẹhin ti o bì Metusela, o si bí ọmọkunrin ati ọmọbinrin: Gbogbo ọjọ́ Enoku si jẹ irinwo ọdún o dí marundilogoji: Enoku si ba Ọlọrun rìn: on kò si sí; nitori ti Ọlọrun mu u lọ.
Kà Gẹn 5
Feti si Gẹn 5
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Gẹn 5:21-24
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò