Eks 1:1-2

Eks 1:1-2 YBCV

NJẸ orukọ awọn ọmọ Israeli, ti o wá si Egipti pẹlu Jakobu ni wọnyi; olukuluku pẹlu ile rẹ̀. Reubeni, Simeoni, Lefi, ati Judah