Efe 1:16

Efe 1:16 YBCV

Emi kò si simi lati mã dupẹ nitori nyin, ati lati mã darukọ nyin ninu adura mi