Iṣe Apo 13:38

Iṣe Apo 13:38 YBCV

Njẹ ki o yé nyin, ará, pe nipasẹ ọkunrin yi li a nwasu idariji ẹ̀ṣẹ fun nyin