Iṣe Apo 13:35

Iṣe Apo 13:35 YBCV

Nitori o si wi ninu Psalmu miran pẹlu pe, Iwọ kì yio jẹ ki Ẹni Mimọ́ rẹ ri idibajẹ.