SAKARAYA 9:12

SAKARAYA 9:12 YCE

Ẹ pada sí ibi ààbò yín, ẹ̀yin tí a kó lẹ́rú lọ tí ẹ sì ní ìrètí; mo ṣèlérí lónìí pé, n óo dá ibukun yín pada ní ìlọ́po meji.