ORIN DAFIDI 92:14-15
ORIN DAFIDI 92:14-15 YCE
Wọn á máa so èso títí di ọjọ́ ogbó wọn, wọn á máa lómi lára, ewé wọn á sì máa tutù nígbà gbogbo; láti fihàn pé olóòótọ́ ni OLUWA; òun ni àpáta mi, kò sì sí aiṣododo lọ́wọ́ rẹ̀.