ORIN DAFIDI 85:10-11

ORIN DAFIDI 85:10-11 YCE

Ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ ati òtítọ́ yóo pàdé; òdodo ati alaafia yóo dì mọ́ ara wọn. Òtítọ́ yóo rú jáde láti inú ilẹ̀; òdodo yóo sì bojú wolẹ̀ láti ojú ọ̀run.