Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín, tí ó mu yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti. Ẹ ya ẹnu yín dáradára, n óo sì bọ yín ní àbọ́yó. “Ṣugbọn àwọn eniyan mi kò gbọ́ràn sí mi lẹ́nu, Israẹli kò sì gba tèmi. Nítorí náà mo fi wọ́n sílẹ̀ sinu agídí ọkàn wọn, kí wọn máa ṣe ohun tó wù wọ́n.
Kà ORIN DAFIDI 81
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 81:10-12
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò