Mo di ẹni àmúpòwe fún ọpọlọpọ eniyan, ṣugbọn ìwọ ni ààbò mi tí ó lágbára. Ẹnu mi kún fún ìyìn rẹ, ó kún fún ògo rẹ tọ̀sán-tòru.
Kà ORIN DAFIDI 71
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 71:7-8
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
YouVersion nlo awọn kuki lati ṣe adani iriri rẹ. Nipa lilo oju opo wẹẹbu wa, o gba lilo awọn kuki wa gẹgẹbi a ti ṣalaye ninu Eto Afihan wa
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò