ORIN DAFIDI 71:23

ORIN DAFIDI 71:23 YCE

N óo máa kígbe fún ayọ̀, nígbà tí mo bá ń kọ orin ìyìn sí ọ; ẹ̀mí mi tí o ti kó yọ, yóo ké igbe ayọ̀.