ORIN DAFIDI 67:1-2

ORIN DAFIDI 67:1-2 YCE

Kí Ọlọrun óo ṣàánú wa, kí ó bukun wa; kí ojú rẹ̀ tan ìmọ́lẹ̀ sí wa lára; kí gbogbo ayé lè mọ ọ̀nà rẹ̀; kí gbogbo orílẹ̀-èdè sì mọ ìgbàlà rẹ̀.