ORIN DAFIDI 30:1-3

ORIN DAFIDI 30:1-3 YCE

N óo yìn ọ́, OLUWA, nítorí pé o ti yọ mí jáde; o kò sì jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi ó yọ̀ mí. OLUWA, Ọlọrun mi, mo ké pè ọ́, o sì wò mí sàn. OLUWA, o ti yọ mí kúrò ninu isà òkú o sọ mí di ààyè láàrin àwọn tí wọ́n ti wọ inú kòtò.