Wúrà ati fadaka ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù fi ṣe oriṣa wọn, iṣẹ́ ọwọ́ eniyan ni wọ́n. Wọ́n lẹ́nu, ṣugbọn wọn kò lè sọ̀rọ̀, wọ́n lójú, ṣugbọn wọn kò lè ríran. Wọ́n létí, ṣugbọn wọn kò lè gbọ́ràn, bẹ́ẹ̀ ni kò sí èémí kan ní ẹnu wọn. Àwọn tí ń ṣe wọ́n yóo dàbí wọn, ati gbogbo àwọn tí ó bá gbẹ́kẹ̀lé wọn.
Kà ORIN DAFIDI 135
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ORIN DAFIDI 135:15-18
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò