ORIN DAFIDI 119:44-45

ORIN DAFIDI 119:44-45 YCE

N óo máa pa òfin rẹ mọ́ nígbà gbogbo, lae ati laelae. N óo máa rìn fàlàlà, nítorí pé mo tẹ̀lé ìlànà rẹ.