ÌWÉ ÒWE 31:20-21

ÌWÉ ÒWE 31:20-21 YCE

Ó lawọ́ sí àwọn talaka, a sì máa ran àwọn aláìní lọ́wọ́. Kì í bẹ̀rù nítorí ìdílé rẹ̀ nígbà òtútù, nítorí gbogbo wọn ni ó ti bá hun aṣọ tí ó móoru.