ÌWÉ ÒWE 30:32

ÌWÉ ÒWE 30:32 YCE

Bí o bá ti ń hùwà òmùgọ̀, tí ò ń gbé ara rẹ ga, tabi tí o tí ń gbèrò ibi, fi òpin sí i, kí o sì ronú.