ÌWÉ ÒWE 3:13-14

ÌWÉ ÒWE 3:13-14 YCE

Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó wá ọgbọ́n rí, ati ẹni tí ó ní òye. Nítorí èrè rẹ̀ dára ju èrè orí fadaka ati ti wúrà lọ.