ÌWÉ ÒWE 25:26-27

ÌWÉ ÒWE 25:26-27 YCE

Olódodo tí ó fi ààyè sílẹ̀ fún eniyan burúkú dàbí odò tí omi rẹ̀ dàrú tabi kànga tí a da ìdọ̀tí sí. Kò dára kí eniyan lá oyin ní àlájù, bẹ́ẹ̀ ni kò dára kí eniyan máa wá iyì ní àwájù.