ÌWÉ ÒWE 19:24-25

ÌWÉ ÒWE 19:24-25 YCE

Ọ̀lẹ ti ọwọ́ bọ àwo oúnjẹ, ṣugbọn kò lè bu oúnjẹ sí ẹnu ara rẹ̀. Na pẹ̀gànpẹ̀gàn eniyan, òpè yóo sì kọ́gbọ́n. Bá olóye wí, yóo sì ní ìmọ̀ sí i.