ÌWÉ ÒWE 19:18-19

ÌWÉ ÒWE 19:18-19 YCE

Bá ọmọ rẹ wí nígbà tí ó sì lè gbọ́ ìbáwí, má sì ṣe wá ìparun rẹ̀. Onínúfùfù yóo jìyà inúfùfù rẹ̀, bí o bá gbà á sílẹ̀ lónìí, o níláti tún gbà á sílẹ̀ lọ́la.