ÌWÉ ÒWE 19:10-12

ÌWÉ ÒWE 19:10-12 YCE

Ìgbádùn kò yẹ òmùgọ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò yẹ kí ẹrú jọba lórí àwọn ìjòyè. Ọgbọ́n kì í jẹ́ kí ọlọ́gbọ́n yára bínú, ògo rẹ̀ sì níláti fojú fo ẹ̀ṣẹ̀ dá. Ibinu ọba dàbí bíbú kinniun, ṣugbọn ojurere rẹ̀ dàbí ìrì lára koríko tútù.