ÌWÉ ÒWE 18:14-15

ÌWÉ ÒWE 18:14-15 YCE

Eniyan lè farada àìsàn, ṣugbọn ta ló lè farada ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn? Ọkàn ọlọ́gbọ́n a máa fẹ́ ìmọ̀, etí ni ọlọ́gbọ́n fi wá a kiri.