ÌWÉ ÒWE 17:4-5

ÌWÉ ÒWE 17:4-5 YCE

Aṣebi a máa tẹ́tí sí ẹni ibi, òpùrọ́ a sì máa fetí sílẹ̀ sí ọ̀rọ̀ ìkà. Ẹni tí ń fi talaka ṣẹ̀sín, ẹlẹ́dàá talaka ní ń tàbùkù, ẹni tí inú rẹ̀ dùn sí wahala ẹni ẹlẹ́ni kò ní lọ láìjìyà.