ÌWÉ ÒWE 16:1-2

ÌWÉ ÒWE 16:1-2 YCE

Èrò ọkàn ni ti eniyan ṣugbọn OLUWA ló ni ìdáhùn. Gbogbo ọ̀nà eniyan ni ó mọ́ lójú ara rẹ̀, ṣugbọn OLUWA ló rí ọkàn.