ÌWÉ ÒWE 14:34-35

ÌWÉ ÒWE 14:34-35 YCE

Òdodo ní ń gbé orílẹ̀-èdè lékè, ṣugbọn ẹ̀ṣẹ̀ jẹ́ ẹ̀gàn fún orílẹ̀-èdè. Iranṣẹ tí ó bá hùwà ọlọ́gbọ́n a máa rí ojurere ọba, ṣugbọn inú a máa bí ọba sí iranṣẹ tí ó bá hùwà ìtìjú.