Òdodo ní ń gbé orílẹ̀-èdè lékè, ṣugbọn ẹ̀ṣẹ̀ jẹ́ ẹ̀gàn fún orílẹ̀-èdè. Iranṣẹ tí ó bá hùwà ọlọ́gbọ́n a máa rí ojurere ọba, ṣugbọn inú a máa bí ọba sí iranṣẹ tí ó bá hùwà ìtìjú.
Kà ÌWÉ ÒWE 14
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: ÌWÉ ÒWE 14:34-35
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò