ÌWÉ ÒWE 14:33

ÌWÉ ÒWE 14:33 YCE

Ọgbọ́n kún inú ẹni tí ó mòye, ṣugbọn kò sí ohun tí ó jọ ọgbọ́n lọ́kàn òmùgọ̀.