ÌWÉ ÒWE 14:28-29

ÌWÉ ÒWE 14:28-29 YCE

Ọ̀pọ̀ eniyan ni ògo ọba, olórí tí kò bá ní eniyan yóo parun. Ẹni tí kì í báá yára bínú lóye lọpọlọpọ, ṣugbọn onínúfùfù ń fi ìwà òmùgọ̀ rẹ̀ hàn.