ÌWÉ ÒWE 11:12-13

ÌWÉ ÒWE 11:12-13 YCE

Ẹni tí ó tẹmbẹlu aládùúgbò rẹ̀ kò gbọ́n, ṣugbọn ọlọ́gbọ́n a máa pa ẹnu mọ́. Olófòófó a máa tú àṣírí, ṣugbọn ẹni tí ó ṣe é gbẹ́kẹ̀lé a máa pa àṣírí mọ́.