NEHEMAYA 6:15

NEHEMAYA 6:15 YCE

A mọ odi náà parí ní ọjọ́ kẹẹdọgbọn oṣù Eluli. Ó gbà wá ní ọjọ́ mejilelaadọta.