NAHUMU Ọ̀rọ̀ Iṣaaju

Ọ̀rọ̀ Iṣaaju
Ìwé Nahumu jẹ́ àkọsílẹ̀ ewì ìdùnnú tí Wolii Nahumu fi sọ ìran tí ó rí nígbà tí ogun kó ìlú Ninefe, tí ó jẹ́ olú-ìlú ilẹ̀ Asiria, ọ̀tá àwọn ọmọ Israẹli. Ní nǹkan bíi ẹẹdẹgbẹrin ọdún kí á tó bí Oluwa wa (7th Century B.C.) ni ogun kó Ninefe tí a sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí. Àwọn ọmọ Israẹli sì gbàgbọ́ pé ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí Ninefe náà jẹ́ ìjẹníyà láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun nítorí ìwà ìkà ati ìgbéraga Ninefe.
Àwọn Ohun tí ó wà ninu Ìwé yìí ní Ìsọ̀rí-ìsọ̀rí
Ìdájọ́ lórí Ninefe 1:1-15
Ìṣubú Ninefe 2:1–3:19

Àwon tá yàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí:

NAHUMU Ọ̀rọ̀ Iṣaaju: YCE

Ìsàmì-sí

Pín

Daako

None

Ṣé o fẹ́ fi àwọn ohun pàtàkì pamọ́ sórí gbogbo àwọn ẹ̀rọ rẹ? Wọlé pẹ̀lú àkántì tuntun tàbí wọlé pẹ̀lú àkántì tí tẹ́lẹ̀