MAKU 3:14-15

MAKU 3:14-15 YCE

Ó bá yan àwọn mejila, ó pè wọ́n ní aposteli, kí wọn lè wà pẹlu rẹ̀, kí ó lè máa rán wọn lọ waasu, kí wọn lè ní àṣẹ láti máa lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.

Àwọn fídíò fún MAKU 3:14-15

Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú MAKU 3:14-15