MATIU 3:1-2

MATIU 3:1-2 YCE

Nígbà tí ó yá, Johanu Onítẹ̀bọmi dé, ó ń waasu ní aṣálẹ̀ Judia. Ó ní, “Ẹ ronupiwada, nítorí ìjọba Ọlọrun fẹ́rẹ̀ dé.”

Àwọn fídíò fún MATIU 3:1-2