MATIU 20:33-34

MATIU 20:33-34 YCE

Wọ́n dá a lóhùn pé, “Oluwa, a fẹ́ kí ojú wa là ni.” Àánú wọn ṣe Jesu, ó bá fi ọwọ́ kàn wọ́n lójú. Wọ́n ríran lẹsẹkẹsẹ, wọ́n bá ń tẹ̀lé e.

Àwọn fídíò fún MATIU 20:33-34