JUDA Ọ̀rọ̀ Iṣaaju

Ọ̀rọ̀ Iṣaaju
Ìdí tí a fi kọ Ìwé láti Ọ̀dọ̀ Juda ni láti kìlọ̀ fún àwọn eniyan nítorí àwọn olùkọ́ni èké kan tí wọn ń pe ara wọn ní onigbagbọ. Ninu ìwé kúkúrú tí ó fara jọ Ìwé Keji Peteru, ẹni tí ó kọ ìwé yìí ń rọ àwọn olùka ìwé náà “láti jà fún igbagbọ tí Ọlọrun ti fún àwọn eniyan rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan gbọ̀n-ọ́n.”
Àwọn Ohun tí ó wà ninu Ìwé yìí ní Ìsọ̀rí-ìsọ̀rí
Ọ̀rọ̀ iṣaaju 1-2
Ìwà, ẹ̀kọ́kẹ́kọ̀ọ́, ati ìparun àwọn olùkọ́ni èké 3-16
Ìgbani-níyànjú láti di igbagbọ mú 17-23
Oore-ọ̀fẹ́ 24-25

Àwon tá yàn lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí:

JUDA Ọ̀rọ̀ Iṣaaju: YCE

Ìsàmì-sí

Pín

Daako

None

Ṣé o fẹ́ fi àwọn ohun pàtàkì pamọ́ sórí gbogbo àwọn ẹ̀rọ rẹ? Wọlé pẹ̀lú àkántì tuntun tàbí wọlé pẹ̀lú àkántì tí tẹ́lẹ̀