“Jobu, n óo dá ọ lóhùn, nítorí pé bí o ti wí yìí, bẹ́ẹ̀ kọ́ lọ̀rọ̀ rí. Ọlọrun ju eniyan lọ. Kí ló dé tí ò ń fi ẹ̀sùn kàn án pé kò ní fèsì kankan sí ọ̀rọ̀ rẹ? Nítorí Ọlọrun sọ̀rọ̀ bákan, ó tún tún un sọ bámìíràn, ṣugbọn kò sí ẹni tí ó yé.
Kà JOBU 33
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: JOBU 33:12-14
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò