JOHANU 15:16-17

JOHANU 15:16-17 YCE

Kì í ṣe ẹ̀yin ni ẹ yàn mí. Èmi ni mo yàn yín, tí mo ran yín pé kí ẹ lọ máa so èso tí kò ní bàjẹ́, kí Baba lè fun yín ní ohunkohun tí ẹ bá bèèrè ní orúkọ mi. Àṣẹ yìí ni mo pa fun yín: ẹ fẹ́ràn ara yín.

Àwọn fídíò fún JOHANU 15:16-17