JOHANU 14:20

JOHANU 14:20 YCE

Ní ọjọ́ náà, ẹ̀yin yóo mọ̀ pé èmi wà ninu Baba mi, ati pé ẹ̀yin wà ninu mi, èmi náà sì wà ninu yín.

Àwọn fídíò fún JOHANU 14:20